F’eru Re F’afefe

Home / Yoruba Hymns / F’eru Re F’afefe

“Ma beru, Emi wa pelu re.” -Gen. 26:24.

1. F’Ẹru Re F’afefe,
N’ireti ma foya
Olorun gbo ‘mikanle rẹ
Oun yoo gb’ori rẹ̀ ga.

2. N’irumi at’iji
Yoo s’ona re fefe
Duro de igba re: oru
Yoo pin s’ojo ayo.

3. Iwo r’ailera wa
Inu wa – n’Iwo mo;
Gbe owo to re si oke,
M’ekun ailera le.

4. K’awa, n’iye n’iku,
So oro Re tantan;
K’a so titi opin emi wa
Ife, itoju Re. Amin.

Check Also

Hosanna s’Omo Dafidi

HOSANNA s’Omo Dafidi “Hosanna s’Omo Dafidi:” -Matthew. 21:9 HOSANNA s’Omo Dafidi Hosanna, ẹ kọrin Olubukun ...

One comment

  1. Are we able to play the music from this Yoruba hymn book or know a website where we can play the music?

Leave a Reply

© Copyright Singaloud.net. All Rights Reserved.