Gbati Mo Ri Agbelebu

Home / Yoruba Hymns / Gbati Mo Ri Agbelebu
Gbati Mo Ri Agbelebu
“… kí á má rí i pé mò ń fọ́nnu kiri àfi nítorí agbelebu Oluwa wa Jesu Kristi” -Galatia 6:14

 1. Gbati mo ri agbelebu
  Ti a kan Oba Ogo mo
  Mo ka gbogbo oro s‘ofo
  Mo kegan gbogbo ogo mi.
 2.  

 3. K‘a mase gbo pe mo nhale
  B‘o ye n‘iku Oluwa mi!
  Gbogbo nkan asan ti mo fe,
  Mo da sile fun eje Re.
 4.  

 5. Wo, lat‘ ori, OWO, ese,
  B‘ikanu at‘ife ti nsan;
  ‘Banuje at‘ ife papo,
  A fegun se ade ogo
 6.  

 7. Gbogbo aye ‘baje t‘emi.
  Ebun abere ni fun mi;
  Ife nla ti nyanilenu
  Gba gbogbo okan, emi mi.
  Amin.


Onkowe: Isaac Watts

Download Gbati Mo Ri Agbelebu (Piano)

»English –  When I Survey The Wondrous Cross


 

Check Also

Gbogbo Ogo, Iyin Ola

Gbogb’ Ogo, Iyin Ola “Hosanna fun Omo Dafidi:” -Matthew. 21:9 Gbogb’ ogo, iyin ola Fun ...

Leave a Reply

© Copyright Singaloud.net. All Rights Reserved.