SingAloud Gospel Lyrics Song

Ninu Irin Ajo Mi Beni Mo Nkorin (A! Mo Fe Ri Jesu)

NINU IRIN AJO MI BENI MO NKORIN

“Olufe, nisinsinyii omo Olorun ni wa. Ohun ti a oo da ko i tii han si wa, bi o ti ri ni awa naa yoo ri, nitori a oo ri i gege bi o ti ri.” -1 John 3:2

 1. Ninu irin ajo mi, beni mo nkorin
  Mo n toka si kalfari, N’ibi eje na
  Idanwo lode ninu, l’ota gbe dide
  Jesu lo nto mi lo, isegun daju

  Egbe:
  A! mo fe ri Jesu kin ma w’oju re,
  Ki nma korin titi nipa ore re
  Ni ilu ogo ni ki ngbohun soke
  Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi.

 2.  

 3. Ninu ise isin mi, b’okunkun basu
  Un o tubo sunmo Jesu, y’o tan imole
  Esu le gb’ogun ti mi, kin le sa pada
  Jesu lo nto mi lo, ko se’wu fun mi.
 4.  

 5. Bi mo tile bo sinu afonifoji
  Imole itoni Re, Yio Mole simi
  Yio na owo re simi, Yio gbe mi soke
  Un o ma tesiwaju, b’o ti nto mi lo
 6.  

 7. Nigbati iji aye yi ba yi lu mi
  Mo ni abo t’o daju, labe apa re
  Y’o ma f’owo re to mi titi de opin
  Ore ododo ni, A! mo ti f’e to.


Onkowe: Rufus H. Cornelius, 1916

Download: A! Mo fe ri Jesu (Piano)
»English – As I Journey Through The Land, Singing As I Go,


SingAloud.net

A unique source for Gospel music, hymns, lyrics and Christian family content that is educational, inspirational, and enjoyable from the light of God’s Word. We welcome advertisement and sponsorship. Please Email or WhatsApp us to advertise with us or promote your Gospel music.

Listen Now

19 comments

Download Gospel Live App