Ore-ofe! Ohun

Home / Yoruba Hymns / Ore-ofe! Ohun
Ore-ofe!  Ohun
“O dá wọn láre lọ́fẹ̀ẹ́ nípa ìràpadà tí Kristi Jesu ṣe” -Romu 3:24

 1. Ore ofe! Ohun
  Adun ni l’eti wa
  Gbongbon re y’o gba orun kan
  Aye y’o gbo pelu.
 2.  
  Egbe:
  Ore ofe sa
  N’igbekele mi
  Jesu ku fun araiye
  O ku fun mi pelu.
   

 3. Ore ofe l’o ko
  Oruko mi l’orun
  L’o fi mi fun Od’agutan
  T’O gba iya mi je.
 4.  

 5. Ore ofe to mi
  S’ona alafia
  O ntoju mi l’ojojumo
  Ni irin ajo mi.
 6.  

 7. Ore ofe ko mi
  Bi a ti ‘gbadura
  O pa mi mo titi d’oni
  Ko si je ki nsako.
 8.  

 9. Je k’ore ofe yi
  F’agbara f’okan mi
  Ki nle fi gbogbo ipa mi
  At’ojo mi fun O. Amin.


Onkowe: Philip Doddridge

Download Ore-ofe! Ohun! (Piano)

»English – Grace! ’tis a charming sound!


Check Also

Gbogbo Ogo, Iyin Ola

Gbogb’ Ogo, Iyin Ola “Hosanna fun Omo Dafidi:” -Matthew. 21:9 Gbogb’ ogo, iyin ola Fun ...

Leave a Reply

© Copyright Singaloud.net. All Rights Reserved.